Full Text Available
Note: Clicking the button above will open the full text document at the original institutional repository in a new window.
Ọ̀pọ̀ ọ̀nà ni àwọn onímọ̀ ti dá lábàá fún ṣíṣe àwárí tàbí ìṣèdá ọ̀rọ̀-ìpẹ̀rí nínú èdè Yorùbá, lára wọn ni ìṣàlàyé, ìhùn-prọ́-pọ̀, ìfìṣàpẹẹrẹ, ìlọ́wẹ̀, ọ̀rọ̀-àyálọ̀, ìfẹ́-ìtumọ̀-lójú àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ìfẹ́-ìtumọ̀-lójú ni ó jẹ́ ìwádìí yìí lógún nípa wíwá prọ́-ìpẹ̀rí fún àrùn Kókóró-Àpá-Sọjà-Àrà (KAS...
| Format: | Article |
|---|---|
| Published: |
2021
|
| Subjects: | |
| Tags: |
No Tags, Be the first to tag this record!
|
| LEADER | 00000njm a2000000a 4500 | ||
|---|---|---|---|
| 001 | oai:repository.ui.edu.ng:123456789/12229 | ||
| 042 | |a dc | ||
| 720 | |a Odoje, C. O. |e author | ||
| 260 | |c 2021 | ||
| 520 | |a Ọ̀pọ̀ ọ̀nà ni àwọn onímọ̀ ti dá lábàá fún ṣíṣe àwárí tàbí ìṣèdá ọ̀rọ̀-ìpẹ̀rí nínú èdè Yorùbá, lára wọn ni ìṣàlàyé, ìhùn-prọ́-pọ̀, ìfìṣàpẹẹrẹ, ìlọ́wẹ̀, ọ̀rọ̀-àyálọ̀, ìfẹ́-ìtumọ̀-lójú àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ìfẹ́-ìtumọ̀-lójú ni ó jẹ́ ìwádìí yìí lógún nípa wíwá prọ́-ìpẹ̀rí fún àrùn Kókóró-Àpá-Sọjà-Àrà (KASA) àti Ebola. A ṣe àgbéyẹ̀wò 1572 ọ̀rọ̀ tí Yusuff, Adétúnjí àti Odòjé (2017) jẹ́ olóòtú fìlìmù, a sì fa àwọn tí wọ́n fẹ́ ìtumọ̀ wọn lójú yọ fún iṣẹ́ ìwádìí tí a ṣe. A ṣàwárí pé oríṣìíríṣìí mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni irú àwọn ọ̀rọ̀ yìí; kò sì sí ìyọnu láti ní òye ìtumọ̀ tuntun tí a wá wọ àwọn ọ̀rọ̀ náà lórí wọn. Ó tilẹ̀ mú ìtumọ̀ gbé tán bá àwọn ọ̀rọ̀ tuntun tí a lò wọ́n fún. | ||
| 024 | 8 | |a 2473-4713 | |
| 024 | 8 | |a 2578-692X | |
| 024 | 8 | |a ui_art_odoje-ife-itumo-loju_2019 | |
| 024 | 8 | |a https://repository.ui.edu.ng/handle/123456789/12229 | |
| 653 | |a Kokoro-Apa-Soja-Ara (KASA) | ||
| 653 | |a Ebola | ||
| 245 | 0 | 0 | |a Ife-itumo-loju: Wiwa Ord-iperi Fun Arun Kokoro-Apa-Soja-Ara (KASA) ati Ebola |