Full Text Available
Note: Clicking the button above will open the full text document at the original institutional repository in a new window.
Oríṣìíríṣìí ẹ̀yà àwọn àkójọpọ̀-ọrọ ni ó wà lórí ìṣàpèjúwe àti àmúlò ẹ̀ka ẹ̀kọ́ ìṣọ̀ǹgbúfò. Fernandes ti ṣe àtúnpín ìpèka tí Baker (1995) ṣe ṣùgbọ́n ìṣàtúnpín rẹ̀ yọ ohun tí Ọ̀súndáre pè ní ọ̀gbúfò ẹlẹ́wà-èdè sílẹ̀. Èyí mú kí ó di dandan láti ṣe àtúnpín iṣẹ́ rẹ̀ kí a sì fi ààyè gba àwọn àtòjọ-ọrọ àw...
| Format: | Article |
|---|---|
| Published: |
2019
|
| Subjects: | |
| Tags: |
No Tags, Be the first to tag this record!
|
| Summary: | Oríṣìíríṣìí ẹ̀yà àwọn àkójọpọ̀-ọrọ ni ó wà lórí ìṣàpèjúwe àti àmúlò ẹ̀ka ẹ̀kọ́ ìṣọ̀ǹgbúfò. Fernandes ti ṣe àtúnpín ìpèka tí Baker (1995) ṣe ṣùgbọ́n ìṣàtúnpín rẹ̀ yọ ohun tí Ọ̀súndáre pè ní ọ̀gbúfò ẹlẹ́wà-èdè sílẹ̀. Èyí mú kí ó di dandan láti ṣe àtúnpín iṣẹ́ rẹ̀ kí a sì fi ààyè gba àwọn àtòjọ-ọrọ àwọn ọ̀hùnkòwé ilé Áfíríkà. Ohun tí a ṣe gan-an ni láti ṣe àgbéyẹ̀wò iṣẹ́ Baker àti Fernandes, a sì lò wọ́n láti ṣe àfikún àwọn èròjà ilé Áfíríkà tí a ṣọ̀nù nínú iṣẹ́ wọn. Òpin àbájáde irú ìṣàtúnpín báyìí kò kan ní jẹ́ èròjà ìpèka lásán, yóò fẹ́ àkójọ-ọrọ àdàlórí ẹ̀kọ́ ọ̀gbúfò lójú tó bẹ́ẹ̀ tí àbájáde iṣẹ́ ìwádìí báyìí yóò sì wúlò fún ìkọ́ni àti ìlànilọ́yé. |
|---|