Full Text Available
Note: Clicking the button above will open the full text document at the original institutional repository in a new window.
Oríṣìíríṣìí ẹ̀yà àwọn àkójọpọ̀-ọrọ ni ó wà lórí ìṣàpèjúwe àti àmúlò ẹ̀ka ẹ̀kọ́ ìṣọ̀ǹgbúfò. Fernandes ti ṣe àtúnpín ìpèka tí Baker (1995) ṣe ṣùgbọ́n ìṣàtúnpín rẹ̀ yọ ohun tí Ọ̀súndáre pè ní ọ̀gbúfò ẹlẹ́wà-èdè sílẹ̀. Èyí mú kí ó di dandan láti ṣe àtúnpín iṣẹ́ rẹ̀ kí a sì fi ààyè gba àwọn àtòjọ-ọrọ àw...
| Format: | Article |
|---|---|
| Published: |
2019
|
| Subjects: | |
| Tags: |
No Tags, Be the first to tag this record!
|
| LEADER | 00000njm a2000000a 4500 | ||
|---|---|---|---|
| 001 | oai:repository.ui.edu.ng:123456789/12224 | ||
| 042 | |a dc | ||
| 720 | |a Odoje, C.O. |e author | ||
| 260 | |c 2019 | ||
| 520 | |a Oríṣìíríṣìí ẹ̀yà àwọn àkójọpọ̀-ọrọ ni ó wà lórí ìṣàpèjúwe àti àmúlò ẹ̀ka ẹ̀kọ́ ìṣọ̀ǹgbúfò. Fernandes ti ṣe àtúnpín ìpèka tí Baker (1995) ṣe ṣùgbọ́n ìṣàtúnpín rẹ̀ yọ ohun tí Ọ̀súndáre pè ní ọ̀gbúfò ẹlẹ́wà-èdè sílẹ̀. Èyí mú kí ó di dandan láti ṣe àtúnpín iṣẹ́ rẹ̀ kí a sì fi ààyè gba àwọn àtòjọ-ọrọ àwọn ọ̀hùnkòwé ilé Áfíríkà. Ohun tí a ṣe gan-an ni láti ṣe àgbéyẹ̀wò iṣẹ́ Baker àti Fernandes, a sì lò wọ́n láti ṣe àfikún àwọn èròjà ilé Áfíríkà tí a ṣọ̀nù nínú iṣẹ́ wọn. Òpin àbájáde irú ìṣàtúnpín báyìí kò kan ní jẹ́ èròjà ìpèka lásán, yóò fẹ́ àkójọ-ọrọ àdàlórí ẹ̀kọ́ ọ̀gbúfò lójú tó bẹ́ẹ̀ tí àbájáde iṣẹ́ ìwádìí báyìí yóò sì wúlò fún ìkọ́ni àti ìlànilọ́yé. | ||
| 024 | 8 | |a 1595-1324 | |
| 024 | 8 | |a ui_art_odoje_atunpin_2019 | |
| 024 | 8 | |a https://repository.ui.edu.ng/handle/123456789/12224 | |
| 653 | |a Atunpfn | ||
| 653 | |a Eko Ogbufo | ||
| 653 | |a Akojodo-Oro | ||
| 245 | 0 | 0 | |a Atunpin Akojopo-Oro Adalorf Eko Ogbufo (Reclassification of Corpus Based Translation Study) |